11 “Bèèrè àmì tí ó bá wù ọ́ lọ́wọ́ OLUWA Ọlọrun rẹ–ìbáà jìn bí isà òkú, tabi kí ó ga bí ojú ọ̀run.”
Ka pipe ipin Aisaya 7
Wo Aisaya 7:11 ni o tọ