Aisaya 7:3 BM

3 OLUWA sọ fún Aisaya pé, “Lọ bá Ahasi, ìwọ ati Ṣeari Jaṣubu, ọmọ rẹ, ní òpin ibi tí wọ́n fa omi dé ní ọ̀nà àwọn alágbàfọ̀.

Ka pipe ipin Aisaya 7

Wo Aisaya 7:3 ni o tọ