Aisaya 8:21 BM

21 Wọn yóo kọjá lọ lórí ilẹ̀ náà ninu ìnira ati ebi; nígbà tí ebi bá pa wọ́n, wọn yóo máa kanra, wọn óo gbé ojú wọn sókè, wọn óo sì gbé ọba ati Ọlọrun wọn ṣépè.

Ka pipe ipin Aisaya 8

Wo Aisaya 8:21 ni o tọ