Aisaya 9:5 BM

5 Gbogbo bàtà àwọn ológun, tí ń kilẹ̀ lójú ogun,ati gbogbo ẹ̀wù tí wọ́n ti yí mọ́lẹ̀ ninu ẹ̀jẹ̀ ni a óo dáná sun,iná yóo sì jó wọn run.

Ka pipe ipin Aisaya 9

Wo Aisaya 9:5 ni o tọ