Aisaya 11:16 BM

16 Ọ̀nà tí ó gbòòrò yóo wà láti Asiria, fún ìyókù àwọn eniyan rẹ̀;bí ó ti ṣe wà fún àwọn ọmọ Israẹli,nígbà tí wọn ń bọ̀ láti Ijipti.

Ka pipe ipin Aisaya 11

Wo Aisaya 11:16 ni o tọ