Aisaya 12:1 BM

1 O óo sọ ní ọjọ́ náà pé,“N óo fi ọpẹ́ fún OLUWA,nítorí pé bí ó tilẹ̀ bínú sí mi,inú rẹ̀ ti rọ̀, ó sì tù mí ninu.

Ka pipe ipin Aisaya 12

Wo Aisaya 12:1 ni o tọ