Aisaya 14:27 BM

27 OLUWA àwọn ọmọ ogun ti pinnu;ta ni ó lè yí ìpinnu rẹ̀ pada?Ó ti dáwọ́lé ohun tí ó fẹ́ ṣeta ni lè ká a lọ́wọ́ kò?

Ka pipe ipin Aisaya 14

Wo Aisaya 14:27 ni o tọ