Aisaya 18:4 BM

4 Nítorí pé OLUWA sọ fún mi péòun óo fi pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ wolẹ̀ láti ibi ibùgbé òunbí ìmọ́lẹ̀ ní ọ̀sán gangan,ati bí ìkùukùu ninu ooru ìgbà ìkórè.

Ka pipe ipin Aisaya 18

Wo Aisaya 18:4 ni o tọ