Aisaya 18:3 BM

3 Gbogbo aráyé,ẹ̀yin tí ń gbé orí ilẹ̀ ayé,nígbà tí a bá gbé àsíá sókè lórí àwọn òkè,ẹ wò ó, nígbà tí a bá fun fèrè ogun, ẹ gbọ́.

Ka pipe ipin Aisaya 18

Wo Aisaya 18:3 ni o tọ