Aisaya 25:1 BM

1 OLUWA, ìwọ ni Ọlọrun mi.N óo gbé ọ ga:n óo yin orúkọ rẹ.Nítorí pé o ti ṣe àwọn nǹkan ìyanu,o ti ṣe àwọn ètò láti ìgbà àtijọ́,o mú wọn ṣẹ pẹlu òtítọ́.

Ka pipe ipin Aisaya 25

Wo Aisaya 25:1 ni o tọ