Aisaya 24:23 BM

23 Òṣùpá yóo dààmú,ìtìjú yóo sì bá oòrùn.Nítorí OLUWA àwọn ọmọ-ogun yóo jọbalórí òkè Sioni ati ní Jerusalẹmu.Yóo sì fi ògo rẹ̀ hànníwájú àwọn àgbààgbà wọn.

Ka pipe ipin Aisaya 24

Wo Aisaya 24:23 ni o tọ