Aisaya 29:6 BM

6 Lójijì, kíá,OLUWA àwọn ọmọ ogun yóo dé ba yín,pẹlu ààrá, ati ìdágìrì, ati ariwo ńlá;ati ààjà, ati ìjì líle,ati ahọ́n iná ajónirun.

Ka pipe ipin Aisaya 29

Wo Aisaya 29:6 ni o tọ