Aisaya 37:8 BM

8 Rabuṣake gbọ́ pé ọba Asiria ti kúrò ní Lakiṣi, nítorí náà, ó lọ bá a níbi tí ó ti ń bá àwọn ará Libina jagun.

Ka pipe ipin Aisaya 37

Wo Aisaya 37:8 ni o tọ