Aisaya 42:15 BM

15 N óo sọ àwọn òkè gíga ati àwọn kéékèèké di ilẹ̀,n óo mú kí gbogbo ewéko orí wọn gbẹ;n óo sọ àwọn odò di erékùṣù,n óo sì mú kí àwọn adágún omi gbẹ.

Ka pipe ipin Aisaya 42

Wo Aisaya 42:15 ni o tọ