Aisaya 43:17 BM

17 ẹni tí ó kó kẹ̀kẹ́ ogun ati ẹṣin jáde, ogun, ati àwọn ọmọ-ogun;wọ́n dùbúlẹ̀ wọn kò lè dìde mọ́,wọ́n kú bí iná fìtílà.

Ka pipe ipin Aisaya 43

Wo Aisaya 43:17 ni o tọ