9 Ẹ ranti àwọn nǹkan ti àtijọ́,nítorí pé èmi ni Ọlọrun, kò sí Ọlọrun mìíràn mọ́.Èmi ni Ọlọrun, kò sí ẹni tí ó dà bí mi.
Ka pipe ipin Aisaya 46
Wo Aisaya 46:9 ni o tọ