Aisaya 47:15 BM

15 Bẹ́ẹ̀ ni àwọn tí ẹ jọ ń ṣiṣẹ́ pọ̀ rí sí ọ,àwọn tí ẹ ti jọ ń ṣòwò pọ̀ láti ìgbà èwe rẹ.Olukuluku wọn ti ṣìnà lọ,kò sí ẹni tí yóo gbà ọ́ sílẹ̀.”

Ka pipe ipin Aisaya 47

Wo Aisaya 47:15 ni o tọ