Aisaya 48:1 BM

1 Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí, ẹ̀yin ará ilé Jakọbu,ẹ̀yin tí à ń fi orúkọ Israẹli pè,ọmọ bíbí inú Juda,ẹ̀yin tí ẹ̀ ń forúkọ OLUWA búra,tí ẹ jẹ́wọ́ Ọlọrun Israẹli,ṣugbọn tí kì í ṣe pẹlu òdodo tabi òtítọ́.

Ka pipe ipin Aisaya 48

Wo Aisaya 48:1 ni o tọ