Aisaya 5:26 BM

26 Ó ta àsíá, ó fi pe orílẹ̀-èdè kan tí ó wà ní òkèèrè;ó sì fọn fèrè sí i láti òpin ayé.Wò ó! Àwọn eniyan orílẹ̀-èdè náà ń bọ̀ kíákíá.

Ka pipe ipin Aisaya 5

Wo Aisaya 5:26 ni o tọ