Aisaya 5:29 BM

29 Bíbú wọn dàbí ti kinniun,wọn a bú ramúramù bí ọmọ kinniun,wọn a kígbe, wọn a sì ki ohun ọdẹ wọn mọ́lẹ̀,wọn a gbé e lọ, láìsí ẹni tí ó lè gbà á lọ́wọ́ wọn.

Ka pipe ipin Aisaya 5

Wo Aisaya 5:29 ni o tọ