Aisaya 5:30 BM

30 Wọn óo hó lé Israẹli lórí lọ́jọ́ náàbí ìgbà tí omi òkun ń hó.Bí eniyan bá wọ ilẹ̀ náà yóo rí òkùnkùn ati ìnira.Ìkùukùu rẹ̀ yóo sì bo ìmọ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Aisaya 5

Wo Aisaya 5:30 ni o tọ