23 Àwọn tí ń dá ọ lóró ni yóo rí ibinu mi,àwọn tí ó wí fún ọ pé,‘Bẹ̀rẹ̀ mọ́lẹ̀ kí á gba orí rẹ kọjá;’tí wọ́n sọ ẹ̀yìn rẹ di ilẹ̀ẹ́lẹ̀,tí wọ́n sọ ọ́ di ojú ọ̀nà wọn, tí wọn óo máa gbà kọjá.”
Ka pipe ipin Aisaya 51
Wo Aisaya 51:23 ni o tọ