Aisaya 52:1 BM

1 Jí, Sioni, jí!Gbé agbára rẹ wọ̀ bí aṣọ,gbé ẹwà rẹ wọ̀ bí ẹ̀wù,ìwọ Jerusalẹmu, ìlú mímọ́;nítorí àwọn aláìkọlà ati aláìmọ́, kò ní wọ inú rẹ mọ́.

Ka pipe ipin Aisaya 52

Wo Aisaya 52:1 ni o tọ