2 Dìde, gbọnranù kúrò ninu erùpẹ̀,ìwọ Jerusalẹmu tí ó wà ninu ìdè.Tú okùn tí a dè mọ́ ọ lọ́rùn kúrò,ìwọ Sioni tí ó wà ninu ìdè.
Ka pipe ipin Aisaya 52
Wo Aisaya 52:2 ni o tọ