Aisaya 51:8 BM

8 Ikán yóo jẹ wọ́n bí aṣọ,kòkòrò yóo jẹ wọ́n bí òwú;ṣugbọn ìdáǹdè mi yóo wà títí lae,ìgbàlà mi yóo sì wà láti ìran dé ìran.”

Ka pipe ipin Aisaya 51

Wo Aisaya 51:8 ni o tọ