Aisaya 51:9 BM

9 Jí, jí! Dìde, OLUWA, jí pẹlu agbára;jí bí ìgbà àtijọ́,bí o ti ṣe sí ìran wa látijọ́.Ṣebí ìwọ ni o gé Rahabu wẹ́lẹwẹ̀lẹ,tí o fi idà gún diragoni?

Ka pipe ipin Aisaya 51

Wo Aisaya 51:9 ni o tọ