Aisaya 53:10 BM

10 Sibẹsibẹ, ó wu OLUWA láti pa á lára,ó sì fi í sinu ìbànújẹ́,nígbà tí ó fi ara rẹ̀ rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀;yóo fojú rí ọmọ rẹ̀,ọjọ́ rẹ̀ yóo sì gùn.Ìfẹ́ OLUWA yóo ṣẹ lọ́wọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Aisaya 53

Wo Aisaya 53:10 ni o tọ