Aisaya 53:9 BM

9 Wọ́n tẹ́ ẹ sí ibojì, pẹlu àwọn eniyan burúkú,wọ́n sì sin ín pẹlu ọlọ́rọ̀,bẹ́ẹ̀ ni kò ṣe ẹnikẹ́ni níbi,kò sì sọ̀rọ̀ ẹ̀tàn.

Ka pipe ipin Aisaya 53

Wo Aisaya 53:9 ni o tọ