4 Nítòótọ́, ó ti gbé ìkáàánú wa lọ,ó sì ti ru ìbànújẹ́ wa;sibẹsibẹ a kà á sí ẹni tí a nà,tí a sì jẹ níyà láti ọ̀dọ̀ Ọlọrun.
Ka pipe ipin Aisaya 53
Wo Aisaya 53:4 ni o tọ