Aisaya 53:5 BM

5 Ṣugbọn wọ́n ṣá a lọ́gbẹ́ nítorí àìdára wa,wọ́n pa á lára nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wa;ìyà tí wọ́n fi jẹ ẹ́ ni ó fún wa ní alaafia,nínà tí a nà án ni ó mú wa lára dá.

Ka pipe ipin Aisaya 53

Wo Aisaya 53:5 ni o tọ