Jẹ́nẹ́sísì 1:11 BMY

11 Ọlọ́run sì wí pé, “Jẹ́ kí ilẹ̀ kí ó hu ọ̀gbìn: ewéko ti yóò máa mú èṣo wá àti igi tí yóò máa so èṣo ní irú tirẹ̀, tí ó ní irúgbìn nínú.” Ó sì rí bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 1

Wo Jẹ́nẹ́sísì 1:11 ni o tọ