Jẹ́nẹ́sísì 1:25 BMY

25 Ọlọ́run sì dá ẹranko inú igbó àti ẹran ọ̀sìn gbogbo ní irú tirẹ̀ àti gbogbo ohun alààyè tí ń rìn ní ilẹ̀ ní irú tirẹ̀. Ọlọ́run sì rí i pé ó dára.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 1

Wo Jẹ́nẹ́sísì 1:25 ni o tọ