Jẹ́nẹ́sísì 1:5 BMY

5 Ọlọ́run sì pe ìmọ́lẹ̀ náà ní “Ọ̀sán” àti òkùnkùn ní “Òru.” Àsálẹ́ àti òwúrọ̀ sì jẹ́ ọjọ́ kìn-ín-ní.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 1

Wo Jẹ́nẹ́sísì 1:5 ni o tọ