Jẹ́nẹ́sísì 10:25 BMY

25 Ébérì sì bí ọmọ méjì:ọ̀kan sì ń jẹ́ Pélégì, nítorí ní ìgbà ayé rẹ̀ ni ilẹ̀ ayé pín sí oríṣìíríṣìí ẹ̀yà àti èdè. Orúkọ arákùnrin rẹ̀ ni Jókítanì.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 10

Wo Jẹ́nẹ́sísì 10:25 ni o tọ