Jẹ́nẹ́sísì 10:30 BMY

30 Agbègbè ibi tí wọn ń gbé bẹ̀rẹ̀ láti Méṣà títí dé Ṣéfárì, ní àwọn ilẹ̀ tó kún fún òkè ní ìlà oòrùn.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 10

Wo Jẹ́nẹ́sísì 10:30 ni o tọ