Jẹ́nẹ́sísì 10:32 BMY

32 Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ẹ̀yà ọmọ Nóà gẹ́gẹ́ bí ìran wọn, ní orílẹ̀ èdè wọn. Ní ipaṣẹ̀ wọn ni àwọn ènìyàn ti tàn ká ilẹ̀ ayé lẹ́yìn ìkún omi.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 10

Wo Jẹ́nẹ́sísì 10:32 ni o tọ