Jẹ́nẹ́sísì 10:9 BMY

9 Ó sì jẹ́ ògbójú ọdẹ níwájú Olúwa; nítorí náà ni a ṣe ń wí pé, “Bí Nímúrọ́dù-ògbójú ọdẹ níwájú Olúwa.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 10

Wo Jẹ́nẹ́sísì 10:9 ni o tọ