Jẹ́nẹ́sísì 11:11 BMY

11 Lẹ́yìn tí ó bí Áfákísádì, ó tún wà láàyè fún ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta ọdún (500), ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin mìíràn.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 11

Wo Jẹ́nẹ́sísì 11:11 ni o tọ