Jẹ́nẹ́sísì 11:17 BMY

17 Ébérì sì wà láàyè fún irínwó-ó-lé-ọgbọ̀n ọdún (430) lẹ́yìn tí ó bí Pélégì, ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin mìíràn.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 11

Wo Jẹ́nẹ́sísì 11:17 ni o tọ