Jẹ́nẹ́sísì 11:2 BMY

2 Bí àwọn ènìyàn ṣe ń tẹ̀ṣíwájú lọ sí ìhà ìlà oòrùn, wọ́n rí pẹ̀tẹ́lẹ̀ kan ní ilẹ̀ Sínárì (Bábílónì), wọ́n sì tẹ̀dó ṣíbẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 11

Wo Jẹ́nẹ́sísì 11:2 ni o tọ