Jẹ́nẹ́sísì 11:4 BMY

4 Nígbà náà ni wọ́n wí pé, “Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a tẹ ìlú kan fún ara wa, kí a sì kọ́ ilé-ìṣọ́ kan tí yóò kan ọ̀run, kí á baà lè ní orúkọ (òkìkí) kí a má sì tú káàkiri sórí gbogbo ilẹ̀ ayé.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 11

Wo Jẹ́nẹ́sísì 11:4 ni o tọ