Jẹ́nẹ́sísì 11:6 BMY

6 Olúwa wí pé, “Bí àwọn ènìyàn bá ń jẹ́ ọ̀kan àti èdè kan tí wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe iṣẹ́ yìí, kò sí ohun tí wọ́n gbérò tí wọn kò ní le ṣeyọrí.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 11

Wo Jẹ́nẹ́sísì 11:6 ni o tọ