Jẹ́nẹ́sísì 12:13 BMY

13 Nítorí náà, sọ pé, arábìnrin mi ni ìwọ, wọn yóò sì ṣe mí dáradára, a ó sì dá ẹ̀mí mi sí nítorí tìrẹ.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 12

Wo Jẹ́nẹ́sísì 12:13 ni o tọ