Jẹ́nẹ́sísì 12:16 BMY

16 Ó sì kẹ́ Ábúrámù dáradára nítorí Ṣáráì, Ábúrámù sì ní àgùntàn àti màlúù, akọ àti abo, kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, ìránṣẹ́kùnrin àti ìránṣẹ́bìnrin, pẹ̀lú u ràkunmí.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 12

Wo Jẹ́nẹ́sísì 12:16 ni o tọ