Jẹ́nẹ́sísì 12:19 BMY

19 Èéṣe tí o fi wí pé, ‘Arábìnrin mi ni,’ tí èmi sì fi fẹ́ ẹ gẹ́gẹ́ bí aya? Nítorí náà nísinsin yìí, aya rẹ náà nìyí, mú un kí sì o máa lọ.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 12

Wo Jẹ́nẹ́sísì 12:19 ni o tọ