Jẹ́nẹ́sísì 13:1 BMY

1 Ábúrámù sì gòkè láti Éjíbítì lọ sí Nẹ́gẹ́fù ní ìhà gúsù, pẹ̀lú aya rẹ̀ àti ohun gbogbo tí ó ní àti Lọ́tì pẹ̀lú.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 13

Wo Jẹ́nẹ́sísì 13:1 ni o tọ