Jẹ́nẹ́sísì 13:8 BMY

8 Ábúrámù sì wí fún Lọ́tì pé, “Mo fẹ́ kí a fòpin sí èdè àìyedè tí ó wà láàrin èmi àti ìwọ àti láàrin àwọn darandaran wa, nítorí pé ẹbí ni wá.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 13

Wo Jẹ́nẹ́sísì 13:8 ni o tọ