Jẹ́nẹ́sísì 14:10 BMY

10 Àfonífojì Ṣídímù sì kún fún kòtò ọ̀dà-ilẹ̀, nígbà tí ọba Ṣódómù àti ọba Gòmórà sì ṣá, díẹ̀ nínú àwọn ọkùnrin ogun náà subú sínú àwọn kòtò náà, àwọn tókù sì sálọ sì orí òkè.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 14

Wo Jẹ́nẹ́sísì 14:10 ni o tọ