Jẹ́nẹ́sísì 14:22 BMY

22 Ṣùgbọ́n Ábúrámù dá ọba Ṣódómù lóhùn pé, “Mo ti búra fún Olúwa, Ọlọ́run ọ̀gá ògo, tí ó dá ọ̀run àti ayé, mo sì ti gbọ́wọ́ sókè,

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 14

Wo Jẹ́nẹ́sísì 14:22 ni o tọ