Jẹ́nẹ́sísì 14:8 BMY

8 Nígbà náà ni ọba Ṣódómù, ọba Gòmórà, ọba Ádímà, ọba Ṣébóímù àti ọba Bélà (èyí ni Ṣóárì), kó àwọn ọmọ ogun wọn, wọ́n sì pa ibùdó-ogun wọn sí àfonífojì Ṣídímù,

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 14

Wo Jẹ́nẹ́sísì 14:8 ni o tọ